Àyọkà pàtàkì ọ̀sọ̀ọ̀sẹ̀

Adeniran Ogunsanya QC, SAN (31 January 1918 – 22 November 1996) jẹ́ amòfin àti olóṣèlú ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, tí ó sì tún jẹ́ ọ̀kan pàtàkì lára àwọn olùdásílẹ̀ ẹgbẹ́ òṣèlú Ibadan Peoples Party (IPP). Ó ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí Kọmíṣọ́nà fún ètò ìdájọ́ ati ètò ẹ̀kọ́ fún Ìpínlẹ̀ Èkó ní àsìkò ìṣèjọba alágbádá ẹlẹ́kejì. Òun náà tún ni alága pátá pátá fún ẹgbẹ́ òṣèlú Nigerian People's Party nígbà ayé rẹ̀. Wọ́n bí Adéníran ní ọjọ́ Kọkànlélógún oṣù Kíní ọdún 1918 ní agbègbè ÌkòròdúÌpínlẹ̀ Èkó sí agboolé ọmọ Ọba Sùbérù Ògúnsànyà Ògúntádé tí ó jẹ́ Ọdọ̀fin ti ìlú Ìkòròdú nígbà náà. Adéníran lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ ti Hope Waddell Training Institute ní ìlú Calabar nígbà tí ó ń gbé pẹ̀lú àbúrò bàbá rẹ̀ tí ó jẹ́ òṣìṣẹ́ ìjọba ní ìlú Calaba. Ìjọba fi ẹ̀bùn ẹ̀kọ́-ọ̀fẹ́ dá Adéníra lọ̀lá láti kàwé síwájú si ní ilé-ẹ̀kọ́ King's College tí ó wà ní Ìpínlẹ̀ Èkó látàrí bí ó ṣe peregedé jùlọ pẹ̀lú máàkì tí ó ga jùlọ nínú ìdánwò àṣekágbá ti Standard VI (6) ní ọdún 1937. Ó tẹ̀ siwájú nínú ẹ̀kọ́ rẹ̀, tí ó sì kẹ́kọ̀ọ́ nípa ìmọ̀ òfin ní ilé-ẹ̀kọ́ fásitì ti University of Manchester àti Gray's Inn tí ó jẹ́ ilé-ẹ̀kọ́ ìmọ̀ òfin.

(ìtẹ̀síwájú...)

Ní ọjọ́ òní...

Ọjọ́ 8 Oṣù Kàrún:

Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...

Àwọn aláìsí lóòní...

Ọjọ́ míràn: 06 • 07 • 08 • 09 • 10 | ìyókù...


Ṣé ẹ mọ̀ pé...?

Ìròyìn ìwòyí

Ẹ tún wo ÌròyìnWiki ní èdè Gẹ̀ẹ́sì
Àwòrán ọjọ́ òní

Gúnugún India (Gyps indicus) ní Orchha, Madhya Pradesh, India.

Àwọn Iṣẹ́-ọwọ́ Míràn
Wikimedia Foundation ni ó gba àlejò Wikipedia, egbe-alasepo ti ki se fun ere ti o tun se alejo opo awon ise-owo miran:
Wikiàyásọ
Àkójọ àwọn àmúsọ
Wikiatúmọ̀èdè
Atúmọ̀èdè orísirísi èdè
Wikispecies
Àkójọ àwọn irú ẹ̀dá
Wikinews
Ìròyìn ọ́fẹ̀
Wikisource
Àwọn àkọsíìwé ọ̀fẹ́
Wikimedia Commons
Àwòrán, ìró àti fídéò
Wikifásítì
Èlò ìkọ́ẹ̀kọ́ ọ̀fẹ́
Wikiìwé
Ìwéẹ̀kọ́ àti ìwéàwòṣe ọ̀fẹ́
Meta-Wiki
Ibi àkóso ìṣẹ́-ọwọ́ Wikimedia
Wikidata
Ìbùdó ìmò ọ̀fẹ́


Àkíyèsí! — Àìṣojúṣájú · Ìlànà àyọkà kíkọ · Ẹ̀tọ́àwòkọ · Ìwà títọ́ · Ìṣeéyẹ̀wò · Ìlànà fún kíkọ lẹ́tà Yorùbá


Kíkọ àyọkà — Kíni Wikipedia jẹ́? · Àtúnṣe ojúewé · Àfikún àwòrán · Ìkópa · Tutorial · Àpótí ìdánwò


Ìrànwọ́ Wikipedia — Àwọn ojúewé tuntun · Àwọn àyọkà ọ̀wọ́n · Àwọn ojúewé fún ìyílédèdà · Àwọn àyọkà fún àtúnṣe · Ìṣọrẹ


Nípa Wikipédia — Abẹ́ igi · FAQ · Àwọn oníṣe Wikipedia · Àwọn alámùójútó · Wikimedia · Software · Àwọn statístíkì


Orúkọàyè — Wikipedia

Àwọn èbúté àti ẹ̀ka àyọkà
Àṣà

Lítíréṣọ̀ • Eré-ìdárayá • Fílmù • Orin • Tíátà • Ìṣeròyìn • Tẹlifísàn • Rédíò

Tẹknọ́lọ́jì

Iṣẹ́ẹ̀rọ • Internet • Àfigbébánisọ̀rọ̀ • Kọ̀mpútà

Àwùjọ

Ẹbí • Fàájì • Òfin • Ọ̀rọ̀-òkòwò • Ìnáwó • Ìṣèlú • Ọ̀rọ̀-àwùjọ • Ènìyàn • Ẹ̀kọ́ • Ìmòye

Sáyẹ́nsì

Ìtòràwọ̀ • Òfurufú • Ọ̀gbìn • Sáyẹ́nsì kọ̀mpútà • Físíksì • Ìwòsàn • Àdánidá • Kẹ́místrì • Bàíọ́lọ́jì

Mathimátíkì

Áljẹ́brà • Ìtúwò • Ìṣírò • Ìṣedọ́gba • Jẹ́ọ́mẹ́trì • Nọ́mbà • Tẹ̀ọ́rẹ́mù • Ọgbọ́n

Jẹ́ọ́gráfì

Ayé • Adágún • Orílẹ̀-èdè • Òkun • Orílẹ̀ • Ìlú • Áfríkà • Ásíà • Europe • Gúúsù Amẹ́ríkà • Àríwá Amẹ́ríkà

Ìtàn

Ogun • Orílẹ̀-èdè tẹ́lẹ̀ • Ilẹ̀ọbalúayé • Ọ̀rọ̀-ayéijọ́un

Ìgbésíayé

Olórí orílẹ̀-èdè • Oníṣọ̀nà • Òṣeré • Onímọ̀sáyẹ́nsì • Amòye • Olóṣèlú • Olùkọ̀wé • Oníṣòwò

Ẹ̀sìn àti ìgbàgbọ́

Ẹ̀sìn Yorùbá • Ìmàle • Ẹ̀sìn Krístì • Ìṣebúddhà • Ìṣehíndù

Ìlera

Ìmáralókun • Ìdárayá • Amáralókun • ìtọ́jú ìlera • Àrùn • Ọ̀rọ̀-àjàkálẹ̀àrùn

This article is issued from Wikipedia. The text is licensed under Creative Commons - Attribution - Sharealike. Additional terms may apply for the media files.