Àyọkà pàtàkì ọ̀sọ̀ọ̀sẹ̀
Àwọn ènìyàn tí wọ́n ń ṣe àmúlò Ìjìnnà-síra-ẹni nípa títò lọ́wọọ̀wọ́ láti wọnú ọjà ìgbàlódé ní ìlú London nígbà àjàkálẹ̀ ààrùn èrànkòrónà lọ́dún 2020

Nínú ìmò ètò ìlera ìgboro, ìsúnjìnnà-síra-ẹni láwùjọ tàbí ìsúnjìnnà-síra-ẹni láifarakan-ra (Social distancing lédè gẹ̀ẹ́sì) jẹ́ ìlànà tí kìí ṣe nípa ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ ìlò oògùn pẹ̀lú èròǹgbà láti dènà títànká àjàkálẹ̀ ààrùn nípa jíjìnnà sí ara ẹni lójúkojú láti ṣe àdínkù iye ìgbà tí àwọn ènìyàn lè súnmọ́ ara wọn pẹ́kípẹ́kí. Ó jẹ mọ́ ìṣèdiwọ̀n bí ènìyàn kan ṣe lè jìnnà sí ẹlòmíràn (irú òdiwọ̀n bẹ́ẹ̀ máa ń yàtọ̀ láti ìgbà dé ìgbà àti ní orílẹ̀ èdè kọ̀ọ̀kan) àti yíyẹra fún ìpéjọpọ̀ ọ̀pọ̀ èèyàn. Nípa Ìjìnnà-síra-ẹni, ó ṣe é ṣe kí àdínkù wà fún kíkó àjàkálẹ̀ ààrùn rán ẹni tí kò láàrùn èyí tí ó lè wáyé nípa dídára pọ̀ mọ́ ẹni tí ó ti kó ààrùn, tí èyí yóò sìn ṣe àdínkù iye ẹni tí ààrùn bẹ́ẹ̀ lè pa. A máa ń lo ìlànà yìí pẹ̀lú ìwà ìmọ́tótó èémí àti fífọwọ́ ẹni. Nígbà rògbòdìyàn àjàkálẹ̀ ààrùn ẹ̀rànkòrónà 2019, àjọ ètò ìlera àgbáyé, World Health Organization (WHO) dábàá láti ṣègbè fún Ìjìnnà-síra-ẹni tí ó tako Ìjìnnà-sáwùjọ-eni, láti ṣàlàyé pé Ìjìnnà-síra-ẹni ni ó lè ṣe àdínkù kíkó àjàkálẹ̀ ààrùn náà, àwọn ènìyàn ṣì lè ní ìbáṣepọ̀ tó dára nípa lílo ìmọ̀-ẹ̀rọ. Láti ṣe àdínkù ìkóràn àjàkálẹ̀ ààrùn àti láti dènà iṣẹ́ àṣekúdórógbó fún àwọn elétò ìlera, pàápàá jù lọ nígbà àjàkálẹ̀ ààrùn, ọ̀pọ̀lọpọ̀ òfin Ìjìnnà-sápèéjọ ni wọ́n là kalẹ̀, lára wọn ni títi ilé-ìwé àti àwọn ilé ìjọsìn pa, ìdágbé, ìséra-ẹni dènà àjàkálẹ̀ ààrùn, òfin kónílégbélé àti gbígbégidínà ìpéjọpọ̀ ọ̀pọ̀ ènìyàn. (ìtẹ̀síwájú...)

Ní ọjọ́ òní...
Wilt Chamberlain

Ọjọ́ 12 Oṣù Kẹ̀wá: Ojo ominira ni Equatorial Guinea (1968)

Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...

  • 1932Dick Gregory, alawada ati alakitiyan ara Amerika (al. 2017)
  • 1942Melvin Franklin, American singer (The Temptations) (al. 1995)
  • 1975Marion Jones, American track and field athlete

Àwọn aláìsí lóòní...

Ọjọ́ míràn: 10 · 11 · 12 · 13 · 14 | ìyókù...


Ṣé ẹ mọ̀ pé...?
  • ... Mẹ̀túsélà ni ẹni tí ọjọ́orí rẹ̀ pọ̀jùlọ nínú Bíbélì; ó sọ wípé ó gbé ayé fún ọdún 969?
  • ... Aretha Franklin jẹ́ akọrin, àti onídùrù, tó gbajúmọ̀ bi «ìyáàfin orin soul»?
  • ... Pablo Picasso dá iṣẹ́ọnà tó tó 20.000 lápọpọ̀
  • ... Òṣùwọ̀n Richter jẹ́ ìdá Charles Richter ará Amẹ́ríkà àtí Beno Gutenberg ará Jẹ́mánì?
Ìròyìn ìwòyí

Ẹ tún wo ÌròyìnWiki ní èdè Gẹ̀ẹ́sì
Àwòrán ọjọ́ òní

Ẹtu dúdú ní Tswalu Kalahari Reserve ní Gúúsù Áfríkà.

Àwọn Iṣẹ́-ọwọ́ Míràn
Wikimedia Foundation ni ó gba àlejò Wikipedia, egbe-alasepo ti ki se fun ere ti o tun se alejo opo awon ise-owo miran:
Wikiàyásọ
Àkójọ àwọn àmúsọ
Wikiatúmọ̀èdè
Atúmọ̀èdè orísirísi èdè
Wikispecies
Àkójọ àwọn irú ẹ̀dá
Wikinews
Ìròyìn ọ́fẹ̀
Wikisource
Àwọn àkọsíìwé ọ̀fẹ́
Wikimedia Commons
Àwòrán, ìró àti fídéò
Wikifásítì
Èlò ìkọ́ẹ̀kọ́ ọ̀fẹ́
Wikiìwé
Ìwéẹ̀kọ́ àti ìwéàwòṣe ọ̀fẹ́
Meta-Wiki
Ibi àkóso ìṣẹ́-ọwọ́ Wikimedia
Wikidata
Ìbùdó ìmò ọ̀fẹ́


Àkíyèsí! — Àìṣojúṣájú · Ìlànà àyọkà kíkọ · Ẹ̀tọ́àwòkọ · Ìwà títọ́ · Ìṣeéyẹ̀wò · Ìlànà fún kíkọ lẹ́tà Yorùbá


Kíkọ àyọkà — Kíni Wikipedia jẹ́? · Àtúnṣe ojúewé · Àfikún àwòrán · Ìkópa · Tutorial · Àpótí ìdánwò


Ìrànwọ́ Wikipedia — Àwọn ojúewé tuntun · Àwọn àyọkà ọ̀wọ́n · Àwọn ojúewé fún ìyílédèdà · Àwọn àyọkà fún àtúnṣe · Ìṣọrẹ


Nípa Wikipédia — Abẹ́ igi · FAQ · Àwọn oníṣe Wikipedia · Àwọn alámùójútó · Wikimedia · Software · Àwọn statístíkì


Orúkọàyè — Wikipedia

Àwọn èbúté àti ẹ̀ka àyọkà
Àṣà

Lítíréṣọ̀ • Eré-ìdárayá • Fílmù • Orin • Tíátà • Ìṣeròyìn • Tẹlifísàn • Rédíò

Tẹknọ́lọ́jì

Iṣẹ́ẹ̀rọ • Internet • Àfigbébánisọ̀rọ̀ • Kọ̀mpútà

Àwùjọ

Ẹbí • Fàájì • Òfin • Ọ̀rọ̀-òkòwò • Ìnáwó • Ìṣèlú • Ọ̀rọ̀-àwùjọ • Ènìyàn • Ẹ̀kọ́ • Ìmòye

Sáyẹ́nsì

Ìtòràwọ̀ • Òfurufú • Ọ̀gbìn • Sáyẹ́nsì kọ̀mpútà • Físíksì • Ìwòsàn • Àdánidá • Kẹ́místrì • Bàíọ́lọ́jì

Mathimátíkì

Áljẹ́brà • Ìtúwò • Ìṣírò • Ìṣedọ́gba • Jẹ́ọ́mẹ́trì • Nọ́mbà • Tẹ̀ọ́rẹ́mù • Ọgbọ́n

Jẹ́ọ́gráfì

Ayé • Adágún • Orílẹ̀-èdè • Òkun • Orílẹ̀ • Ìlú • Áfríkà • Ásíà • Europe • Gúúsù Amẹ́ríkà • Àríwá Amẹ́ríkà

Ìtàn

Ogun • Orílẹ̀-èdè tẹ́lẹ̀ • Ilẹ̀ọbalúayé • Ọ̀rọ̀-ayéijọ́un

Ìgbésíayé

Olórí orílẹ̀-èdè • Oníṣọ̀nà • Òṣeré • Onímọ̀sáyẹ́nsì • Amòye • Olóṣèlú • Olùkọ̀wé • Oníṣòwò

Ẹ̀sìn àti ìgbàgbọ́

Ẹ̀sìn Yorùbá • Ìmàle • Ẹ̀sìn Krístì • Ìṣebúddhà • Ìṣehíndù

Ìlera

Ìmáralókun • Ìdárayá • Amáralókun • ìtọ́jú ìlera • Àrùn • Ọ̀rọ̀-àjàkálẹ̀àrùn

This article is issued from Wikipedia. The text is licensed under Creative Commons - Attribution - Sharealike. Additional terms may apply for the media files.